Ṣé Àmúwá Ọlọ́run Làwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀? TẸ̀ Ẹ̣́ Ṣé Àmúwá Ọlọ́run Làwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀? Ọ̀pọ̀ máa ń ronú pé ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé Ọlọ́run ló ń fa àwọn àjálù tó ń ṣẹlẹ̀. Kí ni Bíbélì sọ? Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Fídíò Tó Dá Lórí Bíbélì—Ẹ̀kọ́ Pàtàkì O Tún Lè Wo OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀? Ṣé Ọlọ́run ló ń fi wọ́n jẹ wá níyà? Ṣé Ọlọ́run máa ń ṣèrànwọ́ fáwọn tí àjálù bá? ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Gbà Pé Ká Máa Jìyà? Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń béèrè pé kí ló fà á tí ìkórìíra àti ìyà fi pọ̀ láyé. Bíbélì dáhùn ìbéèrè yìí lọ́nà tó tẹ́ni lọ́rùn tó sì tuni nínú. ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Àjálù Tí Ojú Ọjọ́ Máa Ń Fà? Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ ohun tó o máa ṣe kí àjálù tí ojú ọjọ́ máa ń fà tó ṣẹlẹ̀, tó bá ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ àti lẹ́yìn tó bá ṣẹlẹ̀. ILÉ ÌṢỌ́ Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe? Jésù mọ̀ pé Ìjọba Ọlọ́run nìkan ló lè yanjú ìṣòro ayé yìí. Kí ni Ìjọba yẹn ti ṣe tó jẹ́ ká gbà bẹ́ẹ̀? ILÉ ÌṢỌ́ Ọlọ́run Máa Tó Mú Gbogbo Ìyà Kúrò Báwo la ṣe lè mọ̀ pé Ọlọ́run ò ní pẹ́ fòpin sí ìyà àti ìrẹ́jẹ? Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Gbìyànjú Ẹ̀ Wò Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan lè wá ọ wa láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú rẹ lọ́fẹ̀ẹ́. Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ṣé Àmúwá Ọlọ́run Làwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀? ÀWỌN Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ INÚ BÍBÉLÌ Ṣé Àmúwá Ọlọ́run Làwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀? Yorùbá Ṣé Àmúwá Ọlọ́run Làwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀? https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102020421/univ/art/1102020421_univ_sqr_xl.jpg ebtv