JÍ! May 2013 | Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere
Ọ̀pọ̀ bàbá ló ti rí i pé àwọn ìlànà Bíbélì ń ran àwọn àti ìdílé àwọn lọ́wọ́.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere
Ṣàyẹ̀wò àwọn ìlànà Bíbélì márùn-ún tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè jẹ́ bàbá rere.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bí Ọkọ Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Lílu Ìyàwó Rẹ̀
Báwo ni Bíbélì ṣe lè ran àwọn tó ń hùwà ipa lọ́wọ́ láti yí ìwà wọn pa da?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bí Ẹ Ṣe Lè Yẹra Fún Sísọ Ọ̀rọ̀ Líle Síra Yín
Kí lo lè ṣe tí ọ̀rọ̀ líle bá ti nípa lórí àjọṣe àárín ìwọ àti ẹnìkejì rẹ?
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Fà Sí Ìṣekúṣe
Tó o bá fẹ́ mú inú Ọlọ́run dùn, ṣàyẹ̀wo ojú tí Ọlọ́run fi ń wò ohun tó ń mú ọkàn fà sí ìṣekúṣe?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Bó O Ṣe Lè Máa Fi Òfin Lélẹ̀ Fún Ọmọ Rẹ Tó Ti Ń Bàlágà
Kí lo lè ṣe tí ọmọ rẹ bá sọ pé òfin rẹ ti le jù
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Ní Àìsàn Tó Ò Ń Bá Fínra? (Apá 1)
Àwọn ọ̀dọ́ mẹ́rin sọ ohun tó ń jẹ́ kí wọ́n lè máa fara da àìsàn tó ń ṣe wọ́n, kínú wọn sì máa dùn.