ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ April 2019
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti June 3 sí 30, 2019 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
Ǹjẹ́ Ò Ń Ṣe Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Láṣeyanjú?
Báwo la ṣe lè túbọ̀ já fáfá lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù kí ayọ̀ wa sì túbọ̀ pọ̀ sí i?
Fara Wé Jésù Kó O Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn
Ohun mẹ́ta kan wà tí Jésù ṣe táá jẹ́ káwa náà ní ìbàlẹ̀ ọkàn bá a tiẹ̀ ń kojú ìṣòro.
Rọ̀ Mọ́ Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ipò Táwọn Òkú Wà
Kí la lè ṣe tá ò fi ní lọ́wọ́ nínú àwọn àṣà ìsìnkú tí kò bá Bíbélì mu?
Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Kó O Lè Borí Àwọn Ẹ̀mí Èṣù
Àwọn nǹkan wo la lè ṣe tá ò fi ní kó sọ́wọ́ Sátánì àtàwọn ẹ̀mí èṣù rẹ̀?
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
A Rí “Péálì Kan Tó Níye Lórí Gan-An”
Kà nípa ohun tó mú kí Winston àti Pamela Payne láti Ọsirélíà gbádùn ìgbésí ayé wọn.
Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Báwo làwọn èèyàn nígbà àtijọ́ ṣe máa ń ṣètò láti bá ọkọ̀ ojú omi rìn?