ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ December 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti February 3–​March 2, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 48

Ohun Tá A Kọ́ Nígbà Tí Jésù Pèsè Búrẹ́dì Lọ́nà Ìyanu

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 3-9, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 49

Kí Ló Yẹ Kó O Ṣe Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 10-16, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 50

Ẹ̀yin Òbí, Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Ìgbàgbọ́ Wọn Lè Túbọ̀ Lágbára

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 17-23, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 51

Jèhófà Mọ Ohun Tó Ń Pa Ẹ́ Lẹ́kún

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní February 24–​March 2, 2025.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Gbogbo Ìgbà Ni Mò Ń Kẹ́kọ̀ọ́

Arákùnrin Joel Adams sọ ohun tó ràn án lọ́wọ́ láti fara dà á, tó sì jẹ́ kó máa láyọ̀ bó ṣe ń ṣiṣẹ́ ìsìn Jèhófà fún ohun tó ju ọgọ́rin (80) ọdún lọ.

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Àwọn wo ni “àwọn áńgẹ́lì àyànfẹ́” tí 1 Tímótì 5:21 sọ̀rọ̀ nípa wọn?

Ǹjẹ́ O Rántí?

Nígbà tó o ka àwọn Ilé Ìṣọ́ tó jáde lọ́dún yìí, ṣó o gbádùn ẹ̀? Wò ó bóyá wàá lè rántí ohun tó o kà.

Àwọn Olóòótọ́ Ìránṣẹ́ Jèhófà Máa Ń San Ẹ̀jẹ́ Wọn

Ẹ̀kọ́ wo la lè kọ́ lára Jẹ́fútà àti ọmọbìnrin ẹ̀?