Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tó Lè Fòpin Sí Ìkórìíra

Ohun Tó Lè Fòpin Sí Ìkórìíra

Bíbélì Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run lágbára láti yí ìwà àwọn èèyàn pa dà sí rere. (Hébérù 4:12) Ọ̀pọ̀ èèyàn ló jẹ́ pé ìgbà tí wọ́n kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ni wọ́n dẹni tí kò lẹ́mìí ìkórìíra mọ́. Jẹ́ ká wo ẹ̀kọ́ Bíbélì mẹ́rin tó ti ran ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́wọ́ tí wọn ò fi lẹ́mìí ìkórìíra mọ́.