ILÉ ÌṢỌ́ No. 3 2016 | Nígbà Tí Ẹnì Tó O Nífẹ̀ẹ́ Bá Kú
Ikú lè pa ẹnikẹ́ni nígbàkigbà. Kí la lè ṣe nígbà tí mọ̀lẹ́bí wa kan tàbí ọ̀rẹ́ wa tímọ́tímọ́ kan bá kú?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Nígbà Tí Ẹnì Tó O Nífẹ̀ẹ́ Bá Kú
Báwo la ṣe lè fara dàá tí èèyàn wa bá kú? Ǹjẹ́ ìrètí kankan tiẹ̀ wà fún àwọn èèyàn wa tó ti kú?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ṣé Ó Burú Kéèyàn Ṣọ̀fọ̀?
Táwọn kan bá wá ronú pé o ti ki àṣejù bọ ìbànújẹ́ tó o ní ńkọ́?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bó O Ṣe Lè Fara Da Ọgbẹ́ Ọkàn
Bíbélì sọ àwọn ohun tó gbéṣẹ́ tá a lè ṣe láti tu àwọn èèyàn nínú.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú
Àwọn ọ̀rẹ́ tó sún mọ́ra pàápàá lè má mọ ohun tí ọ̀rẹ́ wọn tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ nílò.
Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Ta ni bàbá Jósẹ́fù? Irú àwọn aṣọ àti aró wo ló wà láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì?
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Mo Kọ́ Láti Bọ̀wọ̀ fún Àwọn Obìnrin Kí N Sì Mọyì Ara Mi
Joseph Ehrenbogen ka ohun kan nínú Bíbélì tó mú kó yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà pátápátá.
TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN
“Mo Múra Tán Láti Lọ”
Yàtọ̀ sí ìgbàgbọ́, Rèbékà tún ní àwọn ànímọ́ rere mí ì.
Ohun Tí Bíbélì Sọ
Ṣé o burú láti pe orúkọ Ọlọ́run?
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Kí Nìdí Tí Àwa Èèyàn Fi Ń Kú?
Ohun tí Bíbélì sọ nípa ìbéèrè yìí máa tù ọ́ nínú, yóò sì jẹ́ kó o ní ìrètí.