Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Mí ì Tó Máa Ran Ìdílé Lọ́wọ́

Ohun Mí ì Tó Máa Ran Ìdílé Lọ́wọ́

INÚ BÍBÉLÌ LA TI LÈ RÍ ÌTỌ́SỌ́NÀ TÓ DÁRA JÙ LỌ tó wúlò fún tọkọtaya, àwọn òbí àtàwọn ọ̀dọ́. Àwọn ìlànà tó wà nínú rẹ̀ máa jẹ́ ká máa ronú lọ́nà tó tọ́, á sì ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe ìpinnu tó tọ́.​—Òwe 1:1-4.

BÍBÉLÌ TÚN DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ PÀTÀKÌ BÍI:

A rọ̀ ẹ́ pé kó o wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí àtàwọn míì nínú Bíbélì. Wo fídíò náà Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? Wo ìlujá yìí tàbí kó o lọ sí ìkànnì www.mt1130.com/yo.