JÍ! No. 5 2016 | Ṣé Jésù Wà Lóòótọ́?
Àwọn ẹ̀rí wo ló fi hàn pé Jésù wà?
OHUN TÓ Ń LỌ LÁYÉ
Nípa Àwọn Ilẹ̀ Amẹ́ríkà
Ìdààmú àti ìwà ipá jẹ́ méjì lára ìṣòro tí àwọn ìlú kan nílẹ̀ Amẹ́ríkà ń fojú winá. Ṣé Bíbélì lè ṣèrànwọ́?
ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ
Kọ́ Ọmọ Rẹ Nípa Ìbálòpọ̀
Àwọn ọmọdé ti wá ń kó sínú ewu ìbálòpọ̀ ju àtẹ̀yìnwá lọ. Kí ni ohun tó yẹ kó o mọ̀, kí lo sì lè ṣe láti dáàbò ọmọ rẹ̀?
Kẹ́míkà Àgbàyanu Tó Ń Jẹ́ Carbon
Kò sí nǹkan mí ì tó ṣàǹfààní fún ìwàláàyè àwọn nǹkan ẹlẹ́mìí bíi carbon. Kí nìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀, kó ló sì mú kó ṣe pàtàkì?
OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ
Ẹ̀mí Ìmoore
Ọ̀pọ̀ àǹfààní ló wà nínú kéèyàn jẹ́ ẹni tó moore. Àǹfààní wo ló wà níbẹ̀ àti pé báwo lo ṣe lè ní irú ẹ̀mí yẹn?
ÌTÀN ÀTIJỌ́
Aristotle
Ọ̀pọ̀ lára ẹ̀kọ́ àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ló pọ̀ jù lára ẹ̀kọ́ táwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn ayé àtijọ́ fi ń kọ́ni.
“Èyí Mà Rọrùn Gan-an O!”
Àwọn fídíò tó wà ní ìkànnì jw.org ń ṣàǹfààní fún àwọn olùkọ́, agbaninímọ̀ràn àtàwọn mí ì.
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Jẹ́ Ẹni Tó Moore
Báwo lo ṣe lè jẹ́ káwọn tó ràn ẹ́ lọ́wọ́ mọ̀ pé o mọ rírì ohun tí wọ́n ṣe fún ẹ?