ILÉ ÌṢỌ́ September 2012 | Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Jẹ Ọlọ́run Lógún?
Wo ohun tí Bíbélì sọ nípa ojú tí Ọlọ́run fi ń wo àwọn obìnrin àti bí Jésù ṣe ṣe sí àwọn obìnrin.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ìṣòro Tí Àwọn Obìnrin Ń Bá Yí
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Àwọn Obìnrin Tiẹ̀ Jẹ Ọlọ́run Lógún?
Ṣé o rò pé Bíbélì fi ojú kékeré wo àwọn obìnrin. Kọ́ nípa ojú tí Ọlọ́run fi ń wo àwọn obìnrin.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Wọ́n Wà Ní Ipò Ọ̀wọ̀ àti Iyì Lójú Ọlọ́run
Kí la lè kọ́ látinú ọwọ́ tí Jésù fi mú àwọn obìnrin àti bó ṣe ṣe sí wọn?
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Mo Ti Wá Mọ Ọlọ́run Tí Mo Ń Sìn Wàyí
Kọ́ nípa bí pásítọ́ ṣọ́ọ̀ṣí Gba-Jésù ṣe rí òtítọ́ Bíbélì tó ti ń wá..
KẸ́KỌ̀Ọ́ LÁTINÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Kí Ni Yóò Ṣẹlẹ̀ ní Ọjọ́ Ìdájọ́?
Oríṣiríṣi nǹkan ni àwọn èèyàn gbà gbọ́ nípa Ọjọ́ Ìdájọ́. Ṣé ó yẹ ká máa bẹ̀rù rẹ̀? Kí ló máa gbé ṣe?
Inú Rere Ṣe Pàtàkì Lójú Ọlọ́run
Ṣé ó yẹ kó o máa fi inú rere hàn sí gbogbo èèyàn. Ojú wo ni Ọlọ́run fi ń wo ànímọ́ yìí?
SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN
“Àwọn Orílẹ̀-Èdè Yóò Ní Láti Mọ̀ Pé Èmi Ni Jèhófà”
Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń dẹ́bi fún Ọlọ́run pé òun ló ń fa ìwà ìrẹ́jẹ àti ìyà tó wà nínú ayé yìí. Báwo ni Ọlọ́run ṣe máa mú kí orúkọ rẹ̀ di mímọ́?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?
Báwo ni wọ́n ṣe ń fi ìwé ránṣẹ́ láyé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì? Báwo ni ètò káràkátà ṣe rí ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì ìgbàanì?
ÀWỌN ÒǸKÀWÉ WA BÉÈRÈ PÉ
Ǹjẹ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Àwọn Obìnrin Tó Jẹ́ Òjíṣẹ́ Ọlọ́run?
Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ìlànà inú Bíbélì wo ni wọ́n ń tẹ̀ lé? Iṣẹ́ wo ni wọ́n ń jẹ́?
A Lọ Wàásù Ní Ìpẹ̀kun Ilẹ̀ Yúróòpù Níhà Gúúsù
Ìrín-àjò sí Gáfúdò erékùṣù kan tó wà ní gúúsù Kírétè gbádùn mọ́ni.
Orúkọ Ọlọ́run Di Mímọ̀ Ní Èdè Swahili
Kọ́ nípa bí orúkọ Ọlọ́run, ìyẹn Jèhófà, ṣe di èyí tó fara hàn nínú Bíbélì èdè Swahili.
KỌ ỌMỌ RẸ
Géhásì Fi Ojúkòkòrò Ba Ayé Ara Rẹ̀ Jẹ́
Géhásì gba nǹkan tí kìí ṣe tiẹ̀. Ẹ̀kọ́ wo nìyẹn kọ́ wa?