Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ǹjẹ́ èèyàn lè jẹ́ olóòótọ́ nínú ayé oníwà ìbàjẹ́ yìí?

WO OJÚ ÌWÉ 5.

Báwo ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe ran agbo ilé kan tó ń ṣe ẹ̀sìn Híńdù lọ́wọ́?

WO OJÚ ÌWÉ 9 SÍ 11.

Ẹ̀kọ́ pàtàkì wo ni a lè rí kọ́ lára obìnrin olóòótọ́ náà Rúùtù?

WO OJÚ ÌWÉ 19 SÍ 24.

Báwo ni ọkùnrin kan tí ojú rẹ̀ ti ń rí màbo láti kékeré ṣe di ọkọ àti bàbá kan tó ń láyọ̀, tó sì ń bójú tó ìdílé rẹ̀ dáadáa?

WO OJÚ ÌWÉ 26 SÍ 27.