Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Ohun Téèyàn Fi Ń Ṣe Ara Rẹ̀ Léṣe

Ohun Tí Mo Rò—Àwọn Ohun Téèyàn Fi Ń Ṣe Ara Rẹ̀ Léṣe

APÁ 5

Ohun Tí Mo Rò​—Àwọn Ohun Téèyàn Fi Ń Ṣe Ara Rẹ̀ Léṣe

Kọ àwọn ohun tó o rò pé ó lè mú kí sìgá máa wù ẹ́ mu, ohun tó lè sún ẹ mu ọtí ní àmujù tàbí ohun tó lè sún ẹ dé ìdí lílo oògùn olóró, sí ìsàlẹ̀ yìí.

․․․․․

Sọ àwọn ọ̀nà tó o lè fi gbádùn ara rẹ tàbí tó o lè fi pàrònú rẹ́ láìjẹ́ pé o ṣe àwọn ohun tó máa ṣe ara rẹ léṣe.

․․․․․