Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2019-2020—​Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Máa Bá Wa Ṣe

Lo ìtòlẹ́sẹẹsẹ yìí nígbà àpéjọ àyíká táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣe lágbègbè rẹ, kó o lè máa fọkàn bá ìpàdé náà lọ. Ẹṣin ọ̀rọ̀ àpéjọ àyíká yìí ni “Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Pẹ̀lú Gbogbo Ọkàn Rẹ.”

Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Pẹ̀lú Gbogbo Ọkàn Rẹ

Apéjọ yìí máa jẹ́ ká túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ká sì ṣe tán láti fara wa jìn fáwọn míì torí pé a nífẹ̀ẹ́ wọn.

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí nínú àpéjọ àyíká yìí.