Ojúkòkòrò
Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:
Nọ 11:4, 5, 31-33—Ojúkòkòrò mú káwọn ọmọ Ísírẹ́lì kó ẹyẹ àparò tó ju èyí tí wọ́n lè jẹ, Jèhófà sì fìyà jẹ wọ́n torí ohun tí wọ́n ṣe yẹn
2Ọb 5:20-27—Ojúkòkòrò mú kí Géhásì parọ́ mọ́ wòlíì Èlíṣà, ó sì jìyà ohun tó ṣe