Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò
Onírúurú àpilẹ̀kọ títí kan èyí tó máa ń wà ní ìbẹ̀rẹ̀ jw.org ló wà ní abala yìí. Máa kà wọ́n kó o sì máa wo àwọn fídíò tó wà níbẹ̀, ìyẹn á jẹ́ kó túbọ̀ dá ẹ lójú pé àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì máa ń ṣe wá láǹfààní.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìdá Mẹ́ta Nínú Mẹ́rin Àwọn Ẹranko Inú Igbó Ló Ti Kú Láàárín Àádọ́ta (50) Ọdún—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì jẹ́ ká mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sáwọn ẹranko inú igbó lọ́jọ́ iwájú.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Lóòótọ́ ni Ìdíje Olympic Lè Mú Kí Ìṣọ̀kan àti Àlàáfíà Wà Kárí Ayé?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èèyàn ló ń wo bí àwọn olùkópa láti ọgọ́rùn-ún méjì ó lé mẹ́fà (206) orílẹ̀-èdè ṣe ń figagbága nínú ìdíje Olympic ọdún 2024. Ṣé ìdíje yìí lè mú kí àlàáfíà àti ìṣọ̀kan wà?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Wàhálà Tí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú Ń Dá Sílẹ̀ Kárí Ayé—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Gbogbo wàhálà tí ọ̀rọ̀ òṣèlú ń fà máa dópin. Bíbélì jẹ́ ká mọ bí Ọlọ́run ṣe máa ṣeé.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Ìkànnì Àjọlò Ń Ṣàkóbá fún Ọmọ Ẹ?—Bíbélì Lè Ran Àwọn Òbí Lọ́wọ́
Bíbélì sọ ohun táwọn òbí lè ṣe láti dáàbò bo àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ ewu orí ìkànnì àjọlò.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìwà Ọ̀daràn Ń Peléke Sí I Kárí Ayé—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Wàá rí ohun tó ń fa ìwà ọ̀daràn tó ń ṣẹlẹ̀ kárí ayé lónìí.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìwà Ọmọlúàbí Ti Ṣọ̀wọ́n—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Ìwà ọmọlúàbí ṣọ̀wọ́n gan-an lónìí. Bíbélì sọ ìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀, ó sì tún sọ àwọn ohun tá a lè ṣe ká lè jẹ́ ọmọlúàbí.
Ọ̀rọ̀ Ààbò Àwọn Obìnrin—Ohun Tí Bíbélì Sọ
Ọlọ́run ka àwọn obìnrin sí, kò sì fẹ́ kí nǹkan burúkú ṣẹlẹ̀ sí wọn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, wàá rí i pé ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin jẹ Ọlọ́run lógún àti pé ó máa wá nǹkan ṣe sí ìwà ìkà tí wọ́n ń hù sí wọn.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìgbà Wo Ni Gbogbo Ogun Yìí Máa Dópin?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Láìpẹ́ kò ní sí ogun mọ́. Bíbélì sọ bó ṣe máa ṣẹlẹ̀.
Máa Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kó O Má Bàa Dá Wà—Ohun Tí Bíbélì Sọ
Wo ọ̀nà méjì tó o lè gbà ṣe ara ẹ láǹfààní tó o bá ń ran àwọn míì lọ́wọ́.
ÌRÁNTÍ IKÚ JÉSÙ
Jésù Máa Fòpin sí Ìwà Ìkà
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó máa ṣe lọ́jọ́ iwájú?
ÌRÁNTÍ IKÚ JÉSÙ
Jésù Máa Fòpin sí Ipò Òṣì
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó ṣì máa ṣe lọ́jọ́ iwájú?
ÌRÁNTÍ IKÚ JÉSÙ
Jésù Máa Fòpin sí Ogun
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọrírì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó ṣì máa ṣe fún wa?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Wọ́n Ti Ná Ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ Owó Sórí Ogun—Kí Ni Àbárèbábọ̀ Ẹ̀?
Wàá mọ ìdí tàwọn èèyàn ò fi ní máa fi àwọn ohun àmúṣọrọ̀ ayé yìí ja ogun mọ́ àtohun tó máa mú gbogbo àjàlù ti ogun ti fà kúrò.
Tó O Bá Láwọn Ọ̀rẹ́, O Lè Borí Ìṣòro Ìdánìkanwà—Bí Bíbélì Ṣe Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́
Wàá rí ìlànà Bíbélì méjì táá jẹ́ kó o lè borí ìṣòro ìdánìkanwà.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Àwọn Èèyàn Ò Fọkàn Tán Àwọn Olóṣèlú Mọ́—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì rọ̀ wá pé ká kíyè sára ká tó fọkàn tán ẹnì kan, ó sì jẹ́ ká mọ ẹni kan ṣoṣo tó ṣeé fọkàn tán, táá sì yanjú ìṣòro aráyé.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Ogun Àgbáyé Tún Máa Jà?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Kì í ṣe bí ogun á ṣe máa jà káàkiri lákòókò yìí nìkan ni Bíbélì sọ, ó tún sọ bí Ọlọ́run ṣe máa fòpin sí gbogbo ogun.
Ìṣòro Ìdánìkanwà Túbọ̀ Ń Burú Sí I—Kí Ni Bíbélì Sọ
Wàá rí bí àwọn tó máa ń ronú pé àwọn dá wà ṣe lè láyọ̀ nísinsìnyí.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ohun Tó Lè Fi Wá Lọ́kàn Balẹ̀ Lọ́dún 2024—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Àwọn ìlérí tó wà nínú Bíbélì lè jẹ́ kọ́kàn wa balẹ̀ báyìí, ká sì tún máa fojú sọ́nà fún ìgbà tí nǹkan máa dáa lọ́jọ́ iwájú.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Nǹkan Ò Rọrùn Fáwọn Èèyàn Lọ́dún 2023—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì jẹ́ ká mọ ohun táwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ọdún 2023 túmọ̀ sí.
Kí Lo Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé Kò Sẹ́ni Tó Rí Tiẹ̀ Rò?
Wo àwọn ìlànà Bíbélì méjì tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro yìí.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìṣòro Omi Tó Kárí Ayé?
Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe ohun táwọn ìjọba èèyàn ò lè ṣe, ìyẹn kí wọ́n yanjú ìṣòro omi.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Nìdí Tí Kò Fi Sí Àlàáfíà Láyé?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Wàá rí ìdí mẹ́ta táwọn èèyàn ò fi lè fòpin sí ogun.
Bí Huldrych Zwingli Ṣe Wá Òtítọ́ Bíbélì
Ní ọgọ́rùn-ún ọdún kẹrìndínlógún, Zwingli rí ọ̀pọ̀ òtítọ́ inú Bíbélì, ó sì jẹ́ káwọn èèyàn mọ òtítọ́ yìí. Kí la lè kọ́ nínú bó ṣe lo ìgbésí ayé rẹ̀ àti ohun tó gbà gbọ́?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ta Ló Máa Gba Àwọn Aráàlú?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ pé Ọlọ́run máa “fòpin sí ogun kárí ayé.” Báwo ló ṣe máa ṣe é?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Orílẹ̀-Èdè Israel Ni Amágẹ́dọ́nì Ti Máa Bẹ̀rẹ̀?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Ohun tí ìwé Ìfihàn sọ nípa Amágẹ́dọ́nì jẹ́ ká rí ìdáhùn sí ìbéèrè náà.
Ṣé Òtítọ́ Ṣì Lérè?
Nínú ayé tó kún fún irọ́ yìí a lè rí òtítọ́ nínú Bíbélì.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe Sí Ìṣòro Àtijẹ-Àtimu
Ṣó o mo ohun ti Bíbélì sọ nípa ìjọba kan tó máa fòpin sí ìṣòro àtijẹ-àtimu, àtohun tí ìjọba náà á ṣe kí gbogbo èèyàn lè ní nǹkan lọ́gbọọgba?
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe Sáwọn Olóṣèlú Jẹgúdújẹrá
Wàá rí bí alákòóso Ìjọba Ọlọ́run ṣe jẹ́ olóòótọ́, tó sì ṣeé fọkàn tán, kódà alákòóso yìí kò ní ni àwọn èèyàn lára.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Àyíká Tó Ń Bà Jẹ́
Wàá rí bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa fòpin sí ìṣòro àyíká tó ń bà jẹ́.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Àìsàn
Wàá rí bí Ìjọba Ọlọ́run ṣé máa mú ká ní ìlera tó jí pépé.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Ogun
Wàá rí bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa mú kí àlàáfíà àti ààbò wà kárí ayé.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Àìtó Oúnjẹ Tó Kárí Ayé Lónìí?
Ọlọ́run kọ́ ló fà á tí ebi fi ń pa àwa èèyàn, àmọ́ ó kìlọ̀ fún wa pé ó máa ṣẹlẹ̀.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Omíyalé Ṣe Ń Ba Ọ̀pọ̀ Nǹkan Jẹ́ Kárí Ayé?
Wàá rí ohun tí omíyalé tó ń ṣẹlẹ̀ kárí ayé jẹ́ ká mọ̀ nípa àkókò wa yìí.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ogun àti Ojú Ọjọ́ Tó Ń Burú Sí I Túbọ̀ Ń Fa Ọ̀wọ́n Gógó Oúnjẹ Kárí Ayé—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Kì í ṣe pé Bíbélì fún wa nímọ̀ràn tó lè ràn wá lọ́wọ́ nìkan, ó tún jẹ́ ká mọ̀ pé nǹkan máa dáa.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ooru Tó Gbóná Janjan Mú Kárí Ayé Lọ́dún 2023—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé Ọlọ́run ò ní kí ayé yìí pa run.
Bíbélì Lè Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Máa Bọ̀wọ̀ fún Èrò Àwọn Míì
Àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká rí i pé Bíbélì fẹ́ ká wà ní àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn ká sì máa bọ̀wọ̀ fún wọn.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Àwọn Elétò Ìlera Tó Jẹ́ Ọ̀gá Àgbà Kìlọ̀ Pé Ìkànnì Àjọlò Ń Ṣàkóbá Fáwọn Ọ̀dọ́—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Wàá rí ìlànà Bíbélì mẹ́ta tó máa ran àwọn òbí lọ́wọ́ láti dáàbò bo àwọn ọmọ wọn.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Iye Tí Wọ́n Ti Ná Lórí Nǹkan Ìjà Ogun Kárí Ayé Ti Lé Ní Tírílíọ̀nù Méjì Dọ́là—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ pé àwọn orílẹ̀-èdè tó lágbára á máa bá ara wọn fà á kí wọ́n lè tayọ ju ara wọn lọ, wọ́n á sì máa ná òbítíbitì owó kọ́wọ́ wọn lè tẹ ohun tí wọ́n ń wá.
A Mú Ìwé Ìhìn Rere Mátíù àti Jòhánù Jáde ní Èdè Adití ti German
Ní December 18, 2021, a mú ìwé Mátíù àti Jòhánù jáde ní Èdè Adití ti German. Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tá a máa mú odindi ìwé Bíbélì jáde ní èdè yìí.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Àwọn Ètò Kọ̀ǹpútà Tó Lè Dá Ṣiṣẹ́—Ṣé Wọ́n Máa Ṣe Wá Láǹfààní, àbí Wọ́n Máa Dá Kún Ìṣòro Wa?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì jẹ́ ká mọ ìdí tí àwọn onímọ̀ iṣẹ́ ẹ̀rọ kò fi lè fọwọ́ sọ̀yà pé gbogbo ohun táwọn bá ṣe kò ní mú aburú kankan wá
Àǹfààní Tí Ikú Jésù Ṣe Wá
Kí ni ohun méjì tí Jésù jẹ́ ká mọ̀ pé ó ṣe pàtàkì tá a gbọ́dọ̀ ṣe ká tó lè jàǹfààní nínú ikú rẹ̀?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ó Ti Lé Lọ́dún Kan Tí Ogun Ti Ń Jà ní Ukraine—Kí Ni Bíbélì Sọ Pé Ọlọ́run Máa Ṣe?
Kẹ́kọ̀ọ́ sí i kó o lè mọ àwọn nǹkan rere tí Ọlọ́run sọ pé òun máa ṣe nínú Bíbélì láti fòpin sí ogun.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìbànújẹ́ Túbọ̀ Ń Dorí Ọ̀pọ̀ Àwọn Ọ̀dọ́ Kodò—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì sọ ohun táwọn ọ̀dọ́ lè ṣe tí ìbànújẹ́ bá dorí wọn kodò.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ìmìtìtì Ilẹ̀ Tó Runlé-Rùnnà ní Orílẹ̀-Èdè Tọ́kì àti Síríà—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Àwọn tí ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé ní Tọ́kì àti Síríà ba nǹkan wọn jẹ́ tàbí tí wọ́n pàdánù àwọn èèyàn wọn lè rí ìtùnú àti ìrètí gbà nínú Bíbélì.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Àwọn Onímọ̀ Sáyẹ́ǹsì Sọ Pé Àwa Èèyàn Ò Ní Pẹ́ Fọwọ́ Ara Wa Pa Ayé Yìí Run—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa ìparun tó ń bọ̀, ó fi wá lọ́kàn balẹ̀.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Wọ́n Ṣe Pa Ọ̀pọ̀ Èèyàn Nípakúpa Títí Kan Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà?
Ọ̀pọ̀ lẹ̀rù ń bà, torí wọ́n rò pé irú ìpakúpa yẹn tún lè ṣẹlẹ̀.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Táwọn Èèyàn Ò Ní Máa Gbé Ẹ̀yà Kan Ga Ju Ẹ̀yà Míì Lọ?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì ti jẹ́ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn mọ bí wọ́n ṣe lè máa bọ̀wọ̀ fáwọn míì, kí wọ́n sì máa pọ́n wọn lé.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Nìdí Tí Ọ̀rọ̀ Òṣèlú Fi Túbọ̀ Ń Mú Káwọn Èèyàn Kẹ̀yìn Síra?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Ọ̀rọ̀ òṣèlú túbọ̀ ń mú káwọn èèyàn kẹ̀yìn síra wọn kárí ayé. Bíbélì sọ bí ìṣòro yìí ṣe máa yanjú, ó ní alákòóso kan tó máa mú káwọn èèyàn wà níṣọ̀kan.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Bá A Ṣe Wọ Ọdún 2023, Kí Lá Jẹ́ Kọ́kàn Wa Balẹ̀ Pé Ọ̀la Máa Dáa?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń retí ohun tó dáa nínú ọdún tuntun. Ìhìnrere tó wà nínú Bíbélì lè jẹ́ ká ní èrò tó dáa.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
2022: Ọdún Wàhálà àti Ìdàrúdàpọ̀—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì nìkan ló ṣàlàyé ohun táwọn ìṣẹ̀lẹ̀ yìí fi hàn.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Lóòótọ́ Ni Ìdíje Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé Lè Mú Káwọn Èèyàn Ṣe Ara Wọn Lọ́kan?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Eré bọ́ọ̀lù Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé tọdún yìí ju ọ̀rọ̀ eré bọ́ọ̀lù lásán lọ.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Àwọn Orílẹ̀-Èdè Lè Pawọ́ Pọ̀ Yanjú Ìṣòro Ojú Ọjọ́ Tó Ń Burú Sí I?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa ìdí tí ìjọba èèyàn ò fi lè ṣàṣeyọrí.
Àwọn Atúmọ̀ Èdè Méjì Dá Orúkọ Ọlọ́run Pa Dà Sínú Májẹ̀mú Tuntun
Kí nìdí tó fi yẹ kí wọ́n dá orúkọ Ọlọ́run pa dà? Ǹjẹ́ ó tiẹ̀ pọn dandan kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀?
Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú
Téèyàn wa bá kú, ó lè máa ṣe wá bíi pé kò sẹ́ni tó mọ bó ṣe rí lára wa. Àmọ́ Ọlọ́run mọ̀ ọ́n, ó sì fẹ́ tù wá nínú.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Alákòóso Wo Lo Máa Yàn?—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Alákòóso èèyàn tó dáa jù níbi tí agbára ẹ̀ mọ, àmọ́ alákòóso kan wà tó dáńgájíá.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Àwọn Olóṣèlú Ń Kìlọ̀ Pé Ogun Amágẹ́dọ́nì Máa Tó Jà—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Ṣé lílo bọ́ǹbù átọ́míìkì ló máa fa ogun Amágẹ́dọ́nì?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Ọ̀gbẹlẹ̀ Ṣe Túbọ̀ Ń Ṣẹlẹ̀ Kárí Ayé?
Ṣé a lè rí ojútùú ìṣòro yìí? Ṣé ìrètí wà pé nǹkan ṣì máa dáa?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ṣé Ó Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Lọ́wọ́ Sí Ogun—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Ṣé àwọn Kristẹni tó ń lọ́wọ́ sí ogun ń tẹ̀ lé àṣé Jésù?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Ooru Ṣe Ń Mú Gan-an Kárí Ayé?
Ṣé ìgbà kan ń bọ̀ tí ayé yìí ò ní ṣeé gbé mọ́?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Wọ́n Ṣe Ń Yìnbọn Pa Àwọn Èèyàn Nípakúpa Kárí Ayé?
Ṣé ìgbà kan ń bọ̀ tírú ìwà ipá yìí máa dópin?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Àwọn Èèyàn Ṣe Ń Ba Ayé Yìí Jẹ́?
Ẹsẹ Bíbélì kan sọ ohun mẹ́ta nípa ìṣòro ojú ọjọ́ tó ń ba ayé jẹ́.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Nǹkan Ṣe Túbọ̀ Ń Gbówó Lórí Kárí Ayé?
Kí nìdí tí ipò ọrọ̀ ajé fi túbọ̀ ń burú sí i? Báwo ni Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Wọ́n Ṣe Ń Yìnbọn Pa Àwọn Èèyàn Nílé Ìwé?
Kí nìdí táwọn ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú yìí fi ń ṣẹlẹ̀? Ṣé ìwà ipá yìí tiẹ̀ lè dópin?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ogun Tó Ń Jà Ní Ukraine Ti Dá Kún Ìṣòro Àìtó Oúnjẹ
Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ pé àìtó oúnjẹ máa wà, ó sì fún wa láwọn ìmọ̀ràn tó lè ràn wá lọ́wọ́ tá a bá bá ara wa nírú ipò yẹn. Ó tún fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé ọ̀la máa dáa.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Àrùn Kòrónà Ti Pa Mílíọ̀nù Mẹ́fà Èèyàn—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa àjàkálẹ̀ àrùn, ó tún sọ ohun tó lè tù wá nínú àti bí ìṣòro náà ṣe máa yanjú pátápátá.
Àwọn Ìmọ̀ràn Bíbélì Tó Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Tí Iṣẹ́ Bá Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ
Wàá rí ohun mẹ́fà tó o lè ṣe.
Kí Ni Bíbélì Sọ Tẹ́lẹ̀ Nípa Àwọn Ìmìtìtì Ilẹ̀ Tó Lágbára?
Wo àpẹẹrẹ àwọn ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé lẹ́nu àìpẹ́ yìí àti ohun tí Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú.
Ṣé Ìwà Ìbàjẹ́ Tí Àwọn Ìjọba Ń Hù Máa Dópin?
Wàá rí ìdí mẹ́ta tó fi dá wa lójú pé kò ní sí ìwà ìbàjẹ́ lábẹ́ Ìjọba Ọlọ́run.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Lílo Ère Nínú Ìjọsìn?
Ṣé inú Ọlọ́run máa dùn tá a bá ń lò ère nínú ìjọsìn wa?
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ohun Táwọn Ẹlẹ́sìn Ń Ṣe Nípa Ogun Tó Ń Jà Nílẹ̀ Ukraine—Kí Ni Bíbélì Sọ?
Àwọn àlùfáà ṣọ́ọ̀ṣì lórílẹ̀-èdè méjèèjì ń rọ àwọn ọmọ ìjọ wọn pé kí wọ́n ṣe ohun tó yàtọ̀ sí ohun tí Jésù ní káwọn ọmọlẹ́yìn ẹ̀ máa ṣe.
Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!
Ogun Lé Ọ̀pọ̀ Èèyàn Kúrò Lórílẹ̀-Èdè Ukraine
Bíbélì sọ ohun tó fà á gan-an àti bí Ọlọ́run ṣe máa yanjú ìṣòro náà.
Orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Gbógun Wọ Orílẹ̀-èdè Ukraine
Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ṣé Bíbélì sọ ibi táwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ yìí máa já sí?
Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Lílo Oògùn Nílòkulò?
Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́rin tó dá lórí Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro oògùn tó di bárakú fún ẹ.
Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ojú Ọjọ́ Tó Ń Yí Pa Dà àti Ọjọ́ Ọ̀la Wa
Ṣé Ẹlẹ́dàá wa bìkítà nípa ayé àtàwọn tó ń gbébẹ̀?
Ṣé Nǹkan Ṣì Lè Pa Dà sí Bó Ṣe Wà Tẹ́lẹ̀ Ṣáájú Àrùn Corona? Bí Bíbélì Ṣe Lè Ràn Wá Lọ́wọ́
Àwọn ìlànà Bíbélì mẹ́fà tó lè ràn wá lọ́wọ́ láti kojú àwọn nǹkan tó ṣeé ṣe kó ṣẹlẹ̀.
Ṣé Ó Yẹ Káwọn Ẹlẹ́sìn Lọ́wọ́ sí Òṣèlú?
Kárí ayé, ọ̀pọ̀ àwọn tó pera wọn ní ọmọ ẹ̀yìn Jésù ló ń lọ́wọ́ sí òṣèlú. Ṣé ó yẹ kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀?
Ṣé Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Táwọn Olówó Àtàwọn Tálákà Máa Ní Nǹkan Lọ́gbọọgba?
Ìjọba kan wà tó lè pín nǹkan lọ́gbọọgba, kó sì mú ipò òṣì kúrò.
Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Àjálù Tí Ojú Ọjọ́ Máa Ń Fà?
Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ ohun tó o máa ṣe kí àjálù tí ojú ọjọ́ máa ń fà tó ṣẹlẹ̀, tó bá ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ àti lẹ́yìn tó bá ṣẹlẹ̀.
Ìgbà Wo La Máa Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Afẹ̀míṣòfò?
Títí dìgbà tá a máa bọ́ lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá àtàwọn afẹ̀míṣòfò, Bíbélì sọ ohun méjì tá a lè ṣe láti fara dà á táwọn èèyànkéèyàn bá ṣọṣẹ́.
Ṣé Ayé Ò Ní Pẹ́ Pa Run? Kí Ni Àpókálíìsì?
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Bíbélì sọ pé ayé máa wà títí láé, ayé kan wà tó máa pa run.
Bó O Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Ẹ Lọ́wọ́ Àwọn Ìsọfúnni Tí Kì Í Ṣòótọ́
Ìròyìn tó ń ṣi ni lọ́nà, ìròyìn èké àti àhesọ ọ̀rọ̀ pọ̀ káàkiri, wọ́n sì lè ṣàkóbá fúnni.
Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú
Wo fídíò yìí kó o lè mọ ohun tó o lè ṣe kára lè tù ẹ́ tó o bá ń ṣọ̀fọ̀.
Ṣé A Ṣì Lè Gbára Lé Àwọn Ìlànà Bíbélì Lórí Ohun Tó Tọ́ àti Ohun Tí Kò Tọ́?
Wàá rí ìdí méjì tó fi yẹ ká gbára lé àwọn ìlànà Bíbélì.
Bó O Ṣe Lè Borí Àníyàn
Àwọn ìmọ̀ràn àtàwọn ẹsẹ Bíbélì wo ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí àníyàn?
Ìdí Tó Fi Dá Wa Lójú Pé Ọ̀la Máa Dáa
Kí nìdí táwọn ìlérí tó wà nínú Bíbélì fi yàtọ̀ sáwọn ìlérí táwọn èèyàn máa ń ṣe?
Ṣé Ẹ̀sìn Ti Wá Di Òwò Tó Ń Mówó Rẹpẹtẹ Wọlé?
Àwọn ṣọ́ọ̀ṣì kan wà tí ọ̀pọ̀ àwọn tó ń lọ síbẹ̀ jẹ́ aláìní, ṣùgbọ́n tí àwọn pásítọ̀ wọn ní ọrọ̀ rẹpẹtẹ.
Ohun Méje Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Oúnjẹ Léwu Táá sì Ṣara Lóore
Ìwàláàyè jẹ́ ẹ̀bùn, a sì ń fi hàn pé a mọrírì rẹ̀ tá a bá ń bójú tó ìlera wa àti ti ìdílé wa. Ronú nípa ọ̀nà tó o lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀.
Ta Ló Máa Tún Ayé Yìí Ṣe?
Àwọn kan tó jẹ́ onímọ̀ nípa àyíká sọ pé ohun táwọn èèyàn ń ṣe sí ayé lè mú kí onírúurú ẹ̀dá alààyè pòórá pátápátá lórí ilẹ̀ ayé ó sì ń ṣèpalára fún àyíká àtàwọn ẹranko ju ti ìgbàkígbà rílọ.
Ohun Tó O Lè Ṣe tí Àjàkálẹ̀ Àrùn Bá Ṣẹlẹ̀
Tí àjàkálẹ̀ àrùn bá ṣẹlẹ̀, kí lo lè ṣe tí kò fi ní kó bá ìlera ẹ àti àjọṣe ẹ pẹ̀lú Ọlọ́run, tí wàá sì máa láyọ̀?
Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ran Àwọn Ọkùnrin Tó Ń Ṣàníyàn Lọ́wọ́?
Àníyàn túbọ̀ ń pọ̀ sí i láwọn àkókò tí nǹkan le gan-an yìí. Ṣé Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tó o bá ń kojú ìṣòro àníyàn?
Ohun Tó O Lè Ṣe Kí Àrùn Corona Má Bàa Jẹ́ Kí Nǹkan Tojú Sú Ẹ
Tá ò bá jà fitafita, ó lè bẹ̀rẹ̀ sí í sú wa láti dáàbò bo ara wa lọ́wọ́ àrùn Corona.
Ṣé Ìdájọ́ Òdodo Máa Wà?
Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, tí ẹ̀mí gbogbo èèyàn jọ lójú, ni ìdájọ́ òdodo á ti wá.
Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe ti wà lédè Spanish
Lédè Spanish ọ̀rọ̀ kan lè ní ìtumọ̀ oríṣiríṣi, báwo làwọn tó túmọ̀ Bíbélì náà ṣe ṣeé?
Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Àìsàn Bá Dé Láìròtẹ́lẹ̀
Àwọn ìsọfúnni tó wúlò wo ló wà nínú Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ìlera rẹ bá burú sí i láìròtẹ́lẹ̀?
Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná
Lóòótọ́, nǹkan kì í bára dé téèyàn bá pàdánù iṣẹ́ tó ń mówó wọlé fún un, àmọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì lè ṣèrànwọ́ kéèyàn lè mọ́ bá a ṣe máa ṣọ́ ìwọ̀nba owó tó wà lọ́wọ́ ná.
Bó O Ṣe Lè Yẹra fún Ọtí Àmujù
Àbá márùn-un tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀wọ̀n ara ẹ nídìí ọtí kódà tí nǹkan ò bá tiẹ̀ rọrùn fún ẹ.
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn tí Wọ́n Ń Fìyà Jẹ Nínú Ilé
Mọ̀ pé ìwọ kọ́ lo lẹ̀bi, o ò sì dá wà.
Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Ò Bá Lómìnira Àtijáde Bíi Ti Tẹ́lẹ̀
Tí ohùn kan bá ṣẹlẹ̀ tó ò sì lè kúrò nílé, má ṣe rò pé gbogbo nǹkan máa dàrú, pé o ò lè láyọ̀ àti pé ó lè má sí ọ̀nà àbáyọ.
Ṣé Jòhánù Arinibọmi Wà Lóòótọ́?
Òpìtàn ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní náà Josephus gbà pé Jòhánù Arinibọmi tí gbé ayé rí, torí náà, ó yẹ káwa náà gbà bẹ́ẹ̀.
Àkọsílẹ̀ Ayé Àtijọ́ Kan Jẹ́rìí Sí Ibi Tí Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Kan Ti Wà
Àwọn àpáàdì tí wọ́n hú jáde nílùú Samáríà jẹ́rìí sí i pé òótọ́ làwọn ìtàn tó wà nínú Bíbélì.
Èdìdì Ayé Àtijọ́—Kí Ni Wọ́n?
Kí nìdìí táwọn èdìdì ayé àtijọ́ fi ṣe pàtàkì? Báwo làwọn ọba àtàwọn alákòóso ṣe ń lò wọ́n?
Ṣé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Júù Nígbèkùn Bábílónì Jóòótọ́?
Ṣé àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n gbà pé ohun tí Ọlọ́run sọ nípa ìgbésí ayé àwọn Júù nígbèkùn Bábílónì ṣẹlẹ̀ lóòótọ́?
Àwòrán Tí Wọ́n Gbẹ́ Sára Ògiri ní Íjíbítì Àtijọ́ Ti Ohun Tí Bíbélì Sọ Lẹ́yìn
Kà nípa bí àwòrán kan tó wà ní Íjíbítì àtijọ́ ṣe jẹ́ ká túbọ̀ rí i pé òótọ́ lohun tó wà nínú Bíbélì.
Àwọn Òfin Ọlọ́run Lórí Ìmọ́tótó Là Wọ́n Lójú Gan-an
Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ jàǹfààní gan-an bí wọ́n ṣe ń pa àwọn òfin gíga Ọlọ́run mọ́ lórí ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó.
Àìtó Ẹ̀jẹ̀—Ohun Tó Ń Fà Á, Bó Ṣe Máa Ń Ṣe Àwọn Tó Ní In àti Ìtọ́jú Rẹ̀
Kí là ń pè ní àìtó ẹ̀jẹ̀? Ṣé ó ṣeé dènà, ṣé ó sì ṣeé wò sàn?
Ìwádìí Àwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Rí I Pé Ọba Dáfídì Gbé Láyé Rí Lóòótọ́
Àwọn alárìíwísí kan sọ pé ìtàn àròsọ lásán ni ìtàn Ọba Dáfídì, pé àwọn èèyàn ló hùmọ̀ ẹ̀. Àmọ́, kí làwọn awalẹ̀pìtàn rí?
Ìwé Àfọwọ́kọ Àtijọ́ Kan Ṣètìlẹ́yìn fún Lílo Orúkọ Ọlọ́run
Wo ẹ̀rí tó fi hàn pé orúkọ Ọlọ́run wà nínú “Májẹ̀mú Tuntun.”
Ètò Kíka Bíbélì
Ìbáà jẹ́ ètò Bíbélì kíkà ojoojúmọ́ lò ń wá tàbí ti ọdọọdún tàbí èyí tó wà fẹ́ni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ máa ka Bíbélì, ètò Bíbélì kíkà yìí máa wúlò fún ẹ.
Báwo Ni Ìwàláàyè Ṣe Bẹ̀rẹ̀?
Òótó ibẹ̀ ni pé ọ̀pọ̀ àwọn tó kàwé, títí kan àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ni ò fara mọ́ ọn pé òótọ́ ni ẹ̀kọ́ ẹfolúṣọ̀n.
Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
Bó o ṣe lè wá ẹsẹ ìwé mímọ́ nínú Bíbélì rẹ: Bá a ṣe to àwọn ìwé mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) tó wà nínú Bíbélì síbí ni wọ́n ṣe tò ó tẹ̀ léra nínú ọ̀pọ̀ ìtumọ̀ Bíbélì. Lẹ́yìn orúkọ ìwé, nọ́ńbà tó tẹ̀ lé e ni orí, nọ́ńbà tó wá tẹ̀ lé ìyẹn ni ẹsẹ.
Wọ́n Mọyì Bíbélì
William Tyndale àti Michael Servetus jẹ́ méjì lára àwọn tó fi èmí ara wọn wewu, tí wọn ò sì fi iyì ara wọn láwùjọ pè kí wọ́n lè kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láìka àtakò àti ìhalẹ̀mọ́ni sí.
Wọ́n Mọyì Bíbélì—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale
Àwọn iṣẹ́ tó ṣe fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Bíbélì, a sì ń jàǹfààní látinú ẹ̀ títí dòní.

ABALA ÌBẸ̀RẸ̀
Ọ̀rọ̀ Ààbò Àwọn Obìnrin—Ohun Tí Bíbélì Sọ
Ọlọ́run ka àwọn obìnrin sí, kò sì fẹ́ kí nǹkan burúkú ṣẹlẹ̀ sí wọn. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, wàá rí i pé ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin jẹ Ọlọ́run lógún àti pé ó máa wá nǹkan ṣe sí ìwà ìkà tí wọ́n ń hù sí wọn.
Máa Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kó O Má Bàa Dá Wà—Ohun Tí Bíbélì Sọ
Wo ọ̀nà méjì tó o lè gbà ṣe ara ẹ láǹfààní tó o bá ń ran àwọn míì lọ́wọ́.
ÌRÁNTÍ IKÚ JÉSÙ
Jésù Máa Fòpin sí Ìwà Ìkà
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó máa ṣe lọ́jọ́ iwájú?
ÌRÁNTÍ IKÚ JÉSÙ
Jésù Máa Fòpin sí Ipò Òṣì
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọyì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó ṣì máa ṣe lọ́jọ́ iwájú?
ÌRÁNTÍ IKÚ JÉSÙ
Jésù Máa Fòpin sí Ogun
Báwo la ṣe lè fi hàn pé a mọrírì ohun tí Jésù ti ṣe fún wa àtohun tó ṣì máa ṣe fún wa?
Tó O Bá Láwọn Ọ̀rẹ́, O Lè Borí Ìṣòro Ìdánìkanwà—Bí Bíbélì Ṣe Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́
Wàá rí ìlànà Bíbélì méjì táá jẹ́ kó o lè borí ìṣòro ìdánìkanwà.
Ìṣòro Ìdánìkanwà Túbọ̀ Ń Burú Sí I—Kí Ni Bíbélì Sọ
Wàá rí bí àwọn tó máa ń ronú pé àwọn dá wà ṣe lè láyọ̀ nísinsìnyí.
Kí Lo Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bíi Pé Kò Sẹ́ni Tó Rí Tiẹ̀ Rò?
Wo àwọn ìlànà Bíbélì méjì tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro yìí.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ìṣòro Omi Tó Kárí Ayé?
Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe ohun táwọn ìjọba èèyàn ò lè ṣe, ìyẹn kí wọ́n yanjú ìṣòro omi.
Ṣé Òtítọ́ Ṣì Lérè?
Nínú ayé tó kún fún irọ́ yìí a lè rí òtítọ́ nínú Bíbélì.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe Sí Ìṣòro Àtijẹ-Àtimu
Ṣó o mo ohun ti Bíbélì sọ nípa ìjọba kan tó máa fòpin sí ìṣòro àtijẹ-àtimu, àtohun tí ìjọba náà á ṣe kí gbogbo èèyàn lè ní nǹkan lọ́gbọọgba?
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe Sáwọn Olóṣèlú Jẹgúdújẹrá
Wàá rí bí alákòóso Ìjọba Ọlọ́run ṣe jẹ́ olóòótọ́, tó sì ṣeé fọkàn tán, kódà alákòóso yìí kò ní ni àwọn èèyàn lára.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Àyíká Tó Ń Bà Jẹ́
Wàá rí bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa fòpin sí ìṣòro àyíká tó ń bà jẹ́.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Àìsàn
Wàá rí bí Ìjọba Ọlọ́run ṣé máa mú ká ní ìlera tó jí pépé.
ÀKÀNṢE ÌWÀÁSÙ
Ohun Tí Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe sí Ogun
Wàá rí bí Ìjọba Ọlọ́run ṣe máa mú kí àlàáfíà àti ààbò wà kárí ayé.
Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Àìtó Oúnjẹ Tó Kárí Ayé Lónìí?
Ọlọ́run kọ́ ló fà á tí ebi fi ń pa àwa èèyàn, àmọ́ ó kìlọ̀ fún wa pé ó máa ṣẹlẹ̀.
Bíbélì Lè Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Máa Bọ̀wọ̀ fún Èrò Àwọn Míì
Àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí jẹ́ ká rí i pé Bíbélì fẹ́ ká wà ní àlàáfíà pẹ̀lú gbogbo èèyàn ká sì máa bọ̀wọ̀ fún wọn.
Àwọn Ìmọ̀ràn Bíbélì Tó Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Tí Iṣẹ́ Bá Bọ́ Lọ́wọ́ Ẹ
Wàá rí ohun mẹ́fà tó o lè ṣe.
Kí Ni Bíbélì Sọ Tẹ́lẹ̀ Nípa Àwọn Ìmìtìtì Ilẹ̀ Tó Lágbára?
Wo àpẹẹrẹ àwọn ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé lẹ́nu àìpẹ́ yìí àti ohun tí Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú.
Ṣé Ìwà Ìbàjẹ́ Tí Àwọn Ìjọba Ń Hù Máa Dópin?
Wàá rí ìdí mẹ́ta tó fi dá wa lójú pé kò ní sí ìwà ìbàjẹ́ lábẹ́ Ìjọba Ọlọ́run.
Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Lílo Oògùn Nílòkulò?
Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́rin tó dá lórí Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro oògùn tó di bárakú fún ẹ.
Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ojú Ọjọ́ Tó Ń Yí Pa Dà àti Ọjọ́ Ọ̀la Wa
Ṣé Ẹlẹ́dàá wa bìkítà nípa ayé àtàwọn tó ń gbébẹ̀?
Ṣé Nǹkan Ṣì Lè Pa Dà sí Bó Ṣe Wà Tẹ́lẹ̀ Ṣáájú Àrùn Corona? Bí Bíbélì Ṣe Lè Ràn Wá Lọ́wọ́
Àwọn ìlànà Bíbélì mẹ́fà tó lè ràn wá lọ́wọ́ láti kojú àwọn nǹkan tó ṣeé ṣe kó ṣẹlẹ̀.
Ṣé Ó Yẹ Káwọn Ẹlẹ́sìn Lọ́wọ́ sí Òṣèlú?
Kárí ayé, ọ̀pọ̀ àwọn tó pera wọn ní ọmọ ẹ̀yìn Jésù ló ń lọ́wọ́ sí òṣèlú. Ṣé ó yẹ kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀?
Ṣé Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Táwọn Olówó Àtàwọn Tálákà Máa Ní Nǹkan Lọ́gbọọgba?
Ìjọba kan wà tó lè pín nǹkan lọ́gbọọgba, kó sì mú ipò òṣì kúrò.
Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Àjálù Tí Ojú Ọjọ́ Máa Ń Fà?
Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ ohun tó o máa ṣe kí àjálù tí ojú ọjọ́ máa ń fà tó ṣẹlẹ̀, tó bá ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ àti lẹ́yìn tó bá ṣẹlẹ̀.
Ìgbà Wo La Máa Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Afẹ̀míṣòfò?
Títí dìgbà tá a máa bọ́ lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá àtàwọn afẹ̀míṣòfò, Bíbélì sọ ohun méjì tá a lè ṣe láti fara dà á táwọn èèyànkéèyàn bá ṣọṣẹ́.
Ṣé Ayé Ò Ní Pẹ́ Pa Run? Kí Ni Àpókálíìsì?
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Bíbélì sọ pé ayé máa wà títí láé, ayé kan wà tó máa pa run.
Bó O Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Ẹ Lọ́wọ́ Àwọn Ìsọfúnni Tí Kì Í Ṣòótọ́
Ìròyìn tó ń ṣi ni lọ́nà, ìròyìn èké àti àhesọ ọ̀rọ̀ pọ̀ káàkiri, wọ́n sì lè ṣàkóbá fúnni.
Ṣé A Ṣì Lè Gbára Lé Àwọn Ìlànà Bíbélì Lórí Ohun Tó Tọ́ àti Ohun Tí Kò Tọ́?
Wàá rí ìdí méjì tó fi yẹ ká gbára lé àwọn ìlànà Bíbélì.
Bó O Ṣe Lè Borí Àníyàn
Àwọn ìmọ̀ràn àtàwọn ẹsẹ Bíbélì wo ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí àníyàn?
Ìdí Tó Fi Dá Wa Lójú Pé Ọ̀la Máa Dáa
Kí nìdí táwọn ìlérí tó wà nínú Bíbélì fi yàtọ̀ sáwọn ìlérí táwọn èèyàn máa ń ṣe?
Ṣé Ẹ̀sìn Ti Wá Di Òwò Tó Ń Mówó Rẹpẹtẹ Wọlé?
Àwọn ṣọ́ọ̀ṣì kan wà tí ọ̀pọ̀ àwọn tó ń lọ síbẹ̀ jẹ́ aláìní, ṣùgbọ́n tí àwọn pásítọ̀ wọn ní ọrọ̀ rẹpẹtẹ.
Ta Ló Máa Tún Ayé Yìí Ṣe?
Àwọn kan tó jẹ́ onímọ̀ nípa àyíká sọ pé ohun táwọn èèyàn ń ṣe sí ayé lè mú kí onírúurú ẹ̀dá alààyè pòórá pátápátá lórí ilẹ̀ ayé ó sì ń ṣèpalára fún àyíká àtàwọn ẹranko ju ti ìgbàkígbà rílọ.
Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ran Àwọn Ọkùnrin Tó Ń Ṣàníyàn Lọ́wọ́?
Àníyàn túbọ̀ ń pọ̀ sí i láwọn àkókò tí nǹkan le gan-an yìí. Ṣé Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tó o bá ń kojú ìṣòro àníyàn?
Ohun Tó O Lè Ṣe Kí Àrùn Corona Má Bàa Jẹ́ Kí Nǹkan Tojú Sú Ẹ
Tá ò bá jà fitafita, ó lè bẹ̀rẹ̀ sí í sú wa láti dáàbò bo ara wa lọ́wọ́ àrùn Corona.
Ṣé Ìdájọ́ Òdodo Máa Wà?
Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, tí ẹ̀mí gbogbo èèyàn jọ lójú, ni ìdájọ́ òdodo á ti wá.
Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Àìsàn Bá Dé Láìròtẹ́lẹ̀
Àwọn ìsọfúnni tó wúlò wo ló wà nínú Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ìlera rẹ bá burú sí i láìròtẹ́lẹ̀?
Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná
Lóòótọ́, nǹkan kì í bára dé téèyàn bá pàdánù iṣẹ́ tó ń mówó wọlé fún un, àmọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì lè ṣèrànwọ́ kéèyàn lè mọ́ bá a ṣe máa ṣọ́ ìwọ̀nba owó tó wà lọ́wọ́ ná.
Bó O Ṣe Lè Yẹra fún Ọtí Àmujù
Àbá márùn-un tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀wọ̀n ara ẹ nídìí ọtí kódà tí nǹkan ò bá tiẹ̀ rọrùn fún ẹ.
Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn tí Wọ́n Ń Fìyà Jẹ Nínú Ilé
Mọ̀ pé ìwọ kọ́ lo lẹ̀bi, o ò sì dá wà.
Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Ò Bá Lómìnira Àtijáde Bíi Ti Tẹ́lẹ̀
Tí ohùn kan bá ṣẹlẹ̀ tó ò sì lè kúrò nílé, má ṣe rò pé gbogbo nǹkan máa dàrú, pé o ò lè láyọ̀ àti pé ó lè má sí ọ̀nà àbáyọ.
ÀWỌN MÍÌ
Bí Huldrych Zwingli Ṣe Wá Òtítọ́ Bíbélì
Ní ọgọ́rùn-ún ọdún kẹrìndínlógún, Zwingli rí ọ̀pọ̀ òtítọ́ inú Bíbélì, ó sì jẹ́ káwọn èèyàn mọ òtítọ́ yìí. Kí la lè kọ́ nínú bó ṣe lo ìgbésí ayé rẹ̀ àti ohun tó gbà gbọ́?
A Mú Ìwé Ìhìn Rere Mátíù àti Jòhánù Jáde ní Èdè Adití ti German
Ní December 18, 2021, a mú ìwé Mátíù àti Jòhánù jáde ní Èdè Adití ti German. Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tá a máa mú odindi ìwé Bíbélì jáde ní èdè yìí.
Àwọn Atúmọ̀ Èdè Méjì Dá Orúkọ Ọlọ́run Pa Dà Sínú Májẹ̀mú Tuntun
Kí nìdí tó fi yẹ kí wọ́n dá orúkọ Ọlọ́run pa dà? Ǹjẹ́ ó tiẹ̀ pọn dandan kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀?
Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Nínú
Téèyàn wa bá kú, ó lè máa ṣe wá bíi pé kò sẹ́ni tó mọ bó ṣe rí lára wa. Àmọ́ Ọlọ́run mọ̀ ọ́n, ó sì fẹ́ tù wá nínú.
Àǹfààní Tí Ikú Jésù Ṣe Wá
Kí ni ohun méjì tí Jésù jẹ́ ká mọ̀ pé ó ṣe pàtàkì tá a gbọ́dọ̀ ṣe ká tó lè jàǹfààní nínú ikú rẹ̀?
Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú
Wo fídíò yìí kó o lè mọ ohun tó o lè ṣe kára lè tù ẹ́ tó o bá ń ṣọ̀fọ̀.
Ohun Méje Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Oúnjẹ Léwu Táá sì Ṣara Lóore
Ìwàláàyè jẹ́ ẹ̀bùn, a sì ń fi hàn pé a mọrírì rẹ̀ tá a bá ń bójú tó ìlera wa àti ti ìdílé wa. Ronú nípa ọ̀nà tó o lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀.
Ohun Tó O Lè Ṣe tí Àjàkálẹ̀ Àrùn Bá Ṣẹlẹ̀
Tí àjàkálẹ̀ àrùn bá ṣẹlẹ̀, kí lo lè ṣe tí kò fi ní kó bá ìlera ẹ àti àjọṣe ẹ pẹ̀lú Ọlọ́run, tí wàá sì máa láyọ̀?
Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe ti wà lédè Spanish
Lédè Spanish ọ̀rọ̀ kan lè ní ìtumọ̀ oríṣiríṣi, báwo làwọn tó túmọ̀ Bíbélì náà ṣe ṣeé?
Ṣé Jòhánù Arinibọmi Wà Lóòótọ́?
Òpìtàn ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní náà Josephus gbà pé Jòhánù Arinibọmi tí gbé ayé rí, torí náà, ó yẹ káwa náà gbà bẹ́ẹ̀.
Àkọsílẹ̀ Ayé Àtijọ́ Kan Jẹ́rìí Sí Ibi Tí Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Kan Ti Wà
Àwọn àpáàdì tí wọ́n hú jáde nílùú Samáríà jẹ́rìí sí i pé òótọ́ làwọn ìtàn tó wà nínú Bíbélì.
Èdìdì Ayé Àtijọ́—Kí Ni Wọ́n?
Kí nìdìí táwọn èdìdì ayé àtijọ́ fi ṣe pàtàkì? Báwo làwọn ọba àtàwọn alákòóso ṣe ń lò wọ́n?
Ṣé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Júù Nígbèkùn Bábílónì Jóòótọ́?
Ṣé àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n gbà pé ohun tí Ọlọ́run sọ nípa ìgbésí ayé àwọn Júù nígbèkùn Bábílónì ṣẹlẹ̀ lóòótọ́?
Àwòrán Tí Wọ́n Gbẹ́ Sára Ògiri ní Íjíbítì Àtijọ́ Ti Ohun Tí Bíbélì Sọ Lẹ́yìn
Kà nípa bí àwòrán kan tó wà ní Íjíbítì àtijọ́ ṣe jẹ́ ká túbọ̀ rí i pé òótọ́ lohun tó wà nínú Bíbélì.
Àwọn Òfin Ọlọ́run Lórí Ìmọ́tótó Là Wọ́n Lójú Gan-an
Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ jàǹfààní gan-an bí wọ́n ṣe ń pa àwọn òfin gíga Ọlọ́run mọ́ lórí ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó.
Àìtó Ẹ̀jẹ̀—Ohun Tó Ń Fà Á, Bó Ṣe Máa Ń Ṣe Àwọn Tó Ní In àti Ìtọ́jú Rẹ̀
Kí là ń pè ní àìtó ẹ̀jẹ̀? Ṣé ó ṣeé dènà, ṣé ó sì ṣeé wò sàn?
Ìwádìí Àwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Rí I Pé Ọba Dáfídì Gbé Láyé Rí Lóòótọ́
Àwọn alárìíwísí kan sọ pé ìtàn àròsọ lásán ni ìtàn Ọba Dáfídì, pé àwọn èèyàn ló hùmọ̀ ẹ̀. Àmọ́, kí làwọn awalẹ̀pìtàn rí?
Ìwé Àfọwọ́kọ Àtijọ́ Kan Ṣètìlẹ́yìn fún Lílo Orúkọ Ọlọ́run
Wo ẹ̀rí tó fi hàn pé orúkọ Ọlọ́run wà nínú “Májẹ̀mú Tuntun.”
Ètò Kíka Bíbélì
Ìbáà jẹ́ ètò Bíbélì kíkà ojoojúmọ́ lò ń wá tàbí ti ọdọọdún tàbí èyí tó wà fẹ́ni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ máa ka Bíbélì, ètò Bíbélì kíkà yìí máa wúlò fún ẹ.
Báwo Ni Ìwàláàyè Ṣe Bẹ̀rẹ̀?
Òótó ibẹ̀ ni pé ọ̀pọ̀ àwọn tó kàwé, títí kan àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ni ò fara mọ́ ọn pé òótọ́ ni ẹ̀kọ́ ẹfolúṣọ̀n.
Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
Bó o ṣe lè wá ẹsẹ ìwé mímọ́ nínú Bíbélì rẹ: Bá a ṣe to àwọn ìwé mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) tó wà nínú Bíbélì síbí ni wọ́n ṣe tò ó tẹ̀ léra nínú ọ̀pọ̀ ìtumọ̀ Bíbélì. Lẹ́yìn orúkọ ìwé, nọ́ńbà tó tẹ̀ lé e ni orí, nọ́ńbà tó wá tẹ̀ lé ìyẹn ni ẹsẹ.
Wọ́n Mọyì Bíbélì—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale
Àwọn iṣẹ́ tó ṣe fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Bíbélì, a sì ń jàǹfààní látinú ẹ̀ títí dòní.
Wọ́n Mọyì Bíbélì
William Tyndale àti Michael Servetus jẹ́ méjì lára àwọn tó fi èmí ara wọn wewu, tí wọn ò sì fi iyì ara wọn láwùjọ pè kí wọ́n lè kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láìka àtakò àti ìhalẹ̀mọ́ni sí.
Máà bínú, kò sóhun tó jọ ohun tó ò ń wá.