Ìtàn Ìgbésí Ayé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Kárí ayé, àwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin ti fi ìjọsìn Jèhófà ṣáájú láyé wọn. Ìtàn wọn máa fún ẹ níṣìírí, á sì jẹ́ kí ìgbàgbọ́ ẹ túbọ̀ lágbára.
Ìtàn Ìgbésí Ayé Nínú Àwọn Ìwé Ìròyìn Wa
Wàá rí ìlujá tó o lè fi ka ọ̀pọ̀ ìtàn ìgbésí ayé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó ti jáde nínú Ilé Ìṣọ́ àti Jí! látọdún 1955.
HÅKAN DAVIDSSON
A Kọ́wọ́ Ti Iṣẹ́ Tó Ń Mú Kí Òtítọ́ Bíbélì Gbilẹ̀
Iṣẹ́ ìsìn Jèhófà ni Håkan pinnu láti fayé ẹ̀ ṣe dípò kó máa “jayé kiri.” Lẹ́yìn àádọ́ta ọdún, ó ti fojú ara ẹ̀ rí bí Jèhófà ṣe ń jẹ́ kí ìhìn rere dé ọ̀dọ̀ gbogbo orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà àti ahọ́n.
MILES NORTHOVER
Jèhófà Fi Èrè sí Iṣẹ́ Mi
Èdè àwọn adití tí Miles kọ́ mú kó lè ṣe ọ̀pọ̀ nǹkan. Nígbà tó rónú pa dà sí àádọ́ta ọdún sẹ́yìn, ó rí i pé ìbùkún ńlá ló jé fún òun láti ṣèrànwọ́ fáwọn adití tó wà ní Britain, kò sì kábàámọ̀ pé òun ṣe bẹ́ẹ̀ torí Jèhófà bù kún un gan-an.
ASTER PARKER
Ó Wù Mí Kí N Fi Gbogbo Ayé Mi Sin Jèhófà
Àtikéreré ni Aster ti nífẹ̀ẹ́ òtítọ́. Ojú ẹ̀ rí màbo lẹ́wọ̀n lásìkò tí rògbòdìyàn òṣèlú wáyé ní Etiópíà. Ó sìn ní Bẹ́tẹ́lì, nígbà tó yá ó bí ọmọ mẹ́ta.
JAY CAMPBELL
Mo Ti Wá Dẹni Iyì
Aláàbò ara ni Jay, tálákà paraku ni, kò sì lọ sílé ìwé rárá. Láìka gbogbo ìṣòro tó ní sí, ó ti ran àwọn mẹ́ta lọ́wọ́ títí wọ́n fi ṣèrìbọmi, kò sì dẹwọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.
TAPANI VIITALA
Bí Ọwọ́ Mi Ṣe Tẹ Ohun Tó Wù Mí
Tapani lọ káàkiri orílẹ̀-èdè Finland, Estonia, Latvia àti Lithuania, ó sì ń wàásù ìhìn rere fáwọn adití. Lẹ́yìn ọgọ́ta (60) to ti ṣèrìbọmi, ó ṣì ń fìtara wàásù!
PHYLLIS LIANG
Jèhófà Ti Bù Kún Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Rẹ̀
Onírúurú iṣẹ́ ni Phyllis ti ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà. Bó ṣe múra tán láti lọ síbikíbi tí ètò Ọlọ́run bá rán an lọ, tó sì fara da àwọn ìṣòro tó ní mú kó gbádùn ọ̀pọ̀ ìbùkún. Kódà, àwọn ìbùkún míì wá lọ́nà tí ò lérò.
ELFRIEDE URBAN
Mo Gbádùn Iṣẹ́ Míṣọ́nnárì Tí Mo Fayé Mi Ṣe
Ọwọ́ Elfriede tẹ iṣẹ́ míṣọ́nnárì tó fi ṣe àfojúsùn láti kékeré. Ní báyìí tó ti lo ohun tó ju ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) lẹ́nu iṣẹ́ náà, tó sì ti kojú ọ̀pọ̀ ìṣòro àti ipò tó ń yí pa dà, kò dẹwọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.
CAMILLA ROSAM
Mo Pinnu Pé Màá Ṣègbọràn sí Jèhófà Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Mi
Camilla àti ọkọ ẹ̀ gbà pé kò sóhun tó ṣe pàtàkì tó kéèyàn nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, kó sì máa ṣègbọràn sí ètò rẹ̀.
DAVID MAZA
Ìṣẹ̀lẹ̀ Burúkú Kan Kó Ẹ̀dùn Ọkàn Bá Wa, àmọ́ A Pa Dà Láyọ̀
Bí ìdílé kan ṣe fara da ìṣòro mú kí àwọn míì túbọ̀ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà kí wọ́n sì nírètí nínú rẹ̀.
JESÚS MARTÍN
“Jèhófà Gbà Mí Sílẹ̀ Lákòókò tó Nira Jù Lọ Nígbèésí Ayé Mi”
Láwọn ọdún tí Jesús fí dá wà lọ́gbà ẹ̀wọ̀n tó ṣókùnkùn biribiri sí àwọn ọdún tó fi gbádùn àkànṣe iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún, ó kẹ́kọ̀ọ́ nínú àwọn ìrírí tó ní pé, kéèyàn gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà ló dáa jù lọ.
DORINA CAPARELLI
Bó Tiẹ̀ Jẹ́ Pé Mo Máa Ń Tijú, Iṣẹ́ Yìí Náà Ni Màá Tún Fáyé Mi Ṣe!
Dorina ṣiṣẹ́ aṣáájú-ọ̀nà déédéé, aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, alábòójútó arìnrìn-àjò, ó tún sìn ní Bẹ́tẹ́lì. Ó rántí ohun tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó àádọ́rin (70) ọdún tó ti lò lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún, àwọn ìbùkún tó gbádùn àti bí Jèhófà ṣe ràn án lọ́wọ́.
MILTIADIS STAVROU
“Jèhófà Bójú Tó Wa, Ó sì Tọ́ Wa Sọ́nà Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Wa”
Àwọn ìṣòro tí Milto àti Doris ìyàwó ẹ̀ ní lẹ́nu iṣẹ́ míṣọ́nnárì ní Middle East kọ́ wọn pé Jèhófà nìkan ló yẹ kí wọ́n gbára lé, kì í ṣe ara wọn.
DAYRELL SHARP
Jèhófà Ni Ò Jẹ́ Ká Fà Sẹ́yìn
Láìka àwọn ìṣòro tí wọ́n kojú sí, Dayrell àti Susanne Sharp ran àwọn tó lé ní àádóje lọ́wọ́ láti ṣèrìbọmi.
GEORGIY PORCHULYAN
“Jèhófà Fìfẹ́ Hàn Sí Mi Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Mi”
Ó di Ẹlẹ́rìí Jèhófà níbi tó ti ń wá ìfọ̀kànbalẹ̀. Jèhófà fìfẹ́ hàn sí i ní gbogbo ìgbà tó fi wà ní àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ àti nígbèkùn, ìyẹn sì fún un lókun láti tọ́jú ìyàwó rẹ̀ ọ̀wọ́n.

Máà bínú, kò sóhun tó jọ ohun tó ò ń wá.