IBI TÍ MO KỌ ÈRÒ MI SÍ Fọ́tò Rẹ Lórí Ìkànnì Ń Sọ Irú Ẹni Tó O Jẹ́ TẸ̀ Ẹ̣́ Ìwé yìí máa jẹ́ kó o tún un rò kó o tó gbé fọ́tò sórí ìkànnì. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ ìwé àjákọ Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Gbígbé Fọ́tò Sórí Ìkànnì? Tó o bá ń gbé fọ́tò ẹ sórí ìkànnì, àwọn ọ̀rẹ́ àtàwọn ẹbí ẹ lè rí i, á sì rọrùn láti máa kàn síra yín, àmọ́ ó tún léwu. ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò Máa ṣọ́ra fún ewu lórí ìkànnì tó o bá ń bá àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ṣeré níbẹ̀. ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Ṣó Di Dandan Kéèyàn Púpọ̀ Mọ̀ Mí Lórí Ìkànnì Àjọlò? Àwọn kan máa ń fẹ̀mí ara wọn wewu torí kí wọ́n lè lọ́rẹ̀ẹ́ tó pọ̀. Ṣó yẹ kéèyàn fẹ̀mí ara ẹ̀ wewu torí káwọn èèyàn lè gba tiẹ̀? ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Àkóbá Wo Ni Ìkànnì Àjọlò Lè Ṣe fún Mi? Lílo ìkànnì àjọlò lè di bárakú. Àwọn àbá yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó má bàa kó bá ẹ. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Fọ́tò Rẹ Lórí Ìkànnì Ń Sọ Irú Ẹni Tó O Jẹ́ ÌWÉ ÀJÁKỌ FÚN ÀWỌN Ọ̀DỌ́ Fọ́tò Rẹ Lórí Ìkànnì Ń Sọ Irú Ẹni Tó O Jẹ́ Yorùbá Fọ́tò Rẹ Lórí Ìkànnì Ń Sọ Irú Ẹni Tó O Jẹ́ https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502017140/univ/art/502017140_univ_sqr_xl.jpg