Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìwé Tó Ṣàlàyé Àwọn Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì

Ìwé Tó Ṣàlàyé Àwọn Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì

Ìwé Insight on the Scriptures ṣàlàyé àwọn ọ̀rọ̀ inú Bíbélì, á sì jẹ́ kó o túbọ̀ lóye Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run. Ìwé yìí wúlò gan-an téèyàn bá fẹ́ ṣèwádìí nípa onírúurú nǹkan tí Bíbélì mẹ́nu kàn, irú bíi:

  • àwọn èèyàn

  • àwọn ìlú

  • igi ati ewéko

  • àwọn ẹranko

  • àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì

  • àwọn ọ̀rọ̀ Bíbélì

  • ìwà àti ànímọ́ ẹ̀dá

  • àwọn ọ̀rọ̀ Hébérù, Gírí ìkì àtàwọn èdé míì tí wọ́n fi kọ Bíbélì

  • ìwé kọ̀ọ̀kan nínú Bíbélì

Wàá rí ìwé yìí lórí ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower, o sì lè wa ẹ̀dà PDF apá méjèèjì jáde.