Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Jèhófà Fún Gídíónì Lókun

Báwo ni Jèhófà ṣe ran Gídíónì lọ́wọ́ láti kojú àwọn ọmọ Mídíánì tó ń halẹ̀ mọ́ ọn? Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.