Ẹ̀kọ́ 1: Máa Ṣègbọràn sí Àwọn Òbí Rẹ
Kí nìdí tó fi yẹ ká máa ṣègbọràn sí àwọn òbí wa? Wo bí Kọ́lá ṣe mọ ìdí tó fi ṣe pàtàkì.
O Tún Lè Wo
Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ
Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé
Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.