Ìsọfúnni Ṣókí—Australia
- 26,636,000—Iye àwọn èèyàn
- 71,188—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 726—Iye àwọn ìjọ
- 379—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
BÁ A ṢE Ń RAN ARÁ ÌLÚ LỌ́WỌ́
Wọ́n Ń Tu Àwọn Arúgbó Nínú, Wọ́n sì Ń Fún Wọn Nírètí
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń lọ ṣèbẹ̀wò sí ilé tí wọ́n ti ń tọ́jú arúgbó ní Ọsirélíà.
IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Wíwàásù ní Agbègbè Àdádó—Ọsirélíà
Wo bí ìdílé Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ṣe gbádùn ọ̀sẹ̀ alárinrin tí wọ́n fi rìnrìn-àjò lọ sí ìgbèríko kan nílẹ̀ Ọsirélíà kí wọ́n lè lọ kọ́ àwọn èèyàn ibẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.