Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn TẸ̀ Ẹ̣́ Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn Kọ́ nípa bí Bíbélì ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè tó ṣe pàtàkì nígbèésí ayé. Máà bínú, ètò tó o fi ń wo fídíò kò ṣiṣẹ́. Wa Fídíò Yìí Jáde O Tún Lè Wo NÍPA WA Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá O lè mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN MÁA Ń BÉÈRÈ Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn? Ìtumọ̀ Bíbélì èyíkéyìí tó bá wù ẹ́ lo lè lò láti fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. O sì lè pe gbogbo ìdílé ẹ tàbí kó o pe àwọn ọ̀rẹ́ ẹ wá síbi ìkẹ́kọ̀ọ́ náà. NÍPA WA Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? Níbi gbogbo kárí ayé làwọn èèyàn ti mọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọ́n máa ń ṣe fáwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́. Wo bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é. ÌPÀDÉ Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? Wo bó ṣe máa ń rí tá a bá wà nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba. Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn NÍPA WA Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn Yorùbá Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?—Èyí Tó Gùn https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502013341/univ/art/502013341_univ_sqr_xl.jpg