Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Japan

 

2019-01-15

JAPAN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣèrànwọ́ Fáwọn Tí Omíyalé Dà Láàmú ní Japan

Kò pẹ́ lẹ́yìn tí omíyalé ṣẹlẹ̀ tí àwọn ará tó yọ̀ǹda ara wọn fi bẹ̀rẹ̀ sí í palẹ̀ ìdọ̀tí mọ́, tí wọ́n sì tún ilé àwọn ará àtàwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba tó bà jẹ́ ṣe.

2017-05-31

JAPAN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Yọ̀ǹda Ara Wọn Láti Tún Ilé Tó Lé Ní 300 Ṣe Lẹ́yìn Ìmìtìtì Ilẹ̀ Tó Wáyé ní Japan

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó yọ̀ǹda ara wọn láti ṣiṣẹ́ ìrànwọ́ ti parí iṣẹ́ ńlá tí wọ́n ń ṣe. Wọ́n tún ilé àwọn ará wọn tó bà jẹ́ ṣe.